1 Ẹni tí ó gbé ibi ìkọ̀kọ̀ Ọ̀gá-ògo
2 Èmi yóò sọ nípa ti Olúwa pé,
3 Nítòótọ́ òun yóò gbà mí nínú
4 Òun yóò fi ìyẹ́ rẹ̀ bò mí,
5 Ìwọ kì yóò bẹ̀rù nítorí ẹ̀rù òru,
6 tàbí fún àjàkálẹ̀-ààrùn tí ń rìn kiri ní òkùnkùn,
7 Ẹgbẹ̀rún (1,000) yóò ṣubú ní ẹ̀gbẹ́ rẹ,
8 Ìwọ yóò máa wò ó pẹ̀lú ojú rẹ
9 Nítorí ìwọ fi Olúwa ṣe ààbò rẹ,
10 Búburú kan ki yóò ṣubú lù ọ́,
11 Nítorí yóò fi àṣẹ fún àwọn angẹli nípa tìrẹ
12 wọn yóò gbé ọ sókè ní ọwọ́ wọn,
13 Ìwọ yóò rìn lórí kìnnìún àti paramọ́lẹ̀;
14 “Nítorí ti ìfẹ́ rẹ sí mi, èmi yóò gbà ọ́;
15 Òun yóò pè mí, èmi yóò sì dá a lóhùn;
16 Pẹ̀lú ẹ̀mí gígùn ni èmi yóò fi tẹ́ ẹ lọ́rùn,