Salmos 92

YOR

1 Ohun rere ni láti máa fi ọpẹ́ fún Olúwa

2 láti kéde ìfẹ́ rẹ̀ ní òwúrọ̀

3 lára ohùn èlò orin olókùn mẹ́wàá

4 Nítorí ìwọ ni ó mú inú mi dùn

5 Báwo ni iṣẹ́ rẹ tí tóbi tó, Olúwa?

6 Òpè ènìyàn kò mọ̀ ọ́n,

7 nígbà tí àwọn ènìyàn búburú bá rú jáde bí i koríko

8 Ṣùgbọ́n ìwọ Olúwa ni a ó gbéga títí láé.

9 Nítorí nítòótọ́ àwọn ọ̀tá rẹ,

10 Ìwọ ti gbé ìwo mi ga bí i ti màlúù igbó;

11 Ojú mi ti rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi;

12 Olódodo yóò gbèrú bí i igi ọ̀pẹ,

13 tí a gbìn sí ilé Olúwa,

14 Wọn yóò máa so èso ní ìgbà ogbó,

15 láti fihàn pé, “Ẹni ìdúró ṣinṣin ni Olúwa;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado