1 Ọlọ́run, má ṣe dákẹ́;
2 Wo bí àwọn ọ̀tá rẹ ti ń rọ́kẹ̀kẹ̀ lọ,
3 Pẹ̀lú àrékérekè ni wọn dìtẹ̀ sí àwọn ènìyàn rẹ;
4 Wọn wí pé, “wá, ẹ jẹ́ kí á pa wọ́n run bí orílẹ̀-èdè,
5 Wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú ọkàn kan;
6 Àgọ́ Edomu àti ti àwọn ará Iṣmaeli,
7 Gebali, Ammoni àti Amaleki,
8 Asiria pẹ̀lú ti darapọ̀ mọ́ wọn
9 Ṣe sí wọn bí ìwọ ti ṣe sí Midiani
10 ẹni tí ó ṣègbé ní Endori
11 Ṣe àwọn ọlọ́lá wọn bí Orebu àti Seebu,
12 tí ó wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a gbà ní ìní
13 Ìwọ Ọlọ́run, ṣe wọ́n bí ààjà,
14 Bí iná ti í jó igbó,
15 bẹ́ẹ̀ ni kí o fi ẹ̀fúùfù líle rẹ lépa wọn
16 Fi ìtìjú kún ojú wọn,
17 Jẹ́ kí ojú kí ó tì wọ́n, kí wọ́n sì dààmú láéláé
18 jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ìwọ, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwa: