Salmos 84

YOR

1 Ibùgbé rẹ̀ ti lẹ́wà tó,

2 Ọkàn mi ń ṣàfẹ́rí nítòótọ́

3 Nítòótọ́ ológoṣẹ́ ri ilé,

4 Ìbùkún ní fún àwọn tí ó ń gbé inú ilé rẹ;

5 Ìbùkún ni fún àwọn tí agbára wọn wà nínú rẹ

6 Àwọn tí ń la àfonífojì omijé lọ

7 Wọ́n ń lọ láti ipa dé ipá

8 Gbọ́ àdúrà mi, Olúwa Ọlọ́run Alágbára;

9 Wo asà wa, Ọlọ́run;

10 Dídára ní ọjọ́ kan ní ààfin rẹ

11 Nítorí Olúwa Ọlọ́run jẹ́ òòrùn àti asà;

12 Olúwa àwọn ọmọ-ogun,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado