1 Ọlọ́run ń ṣàkóso nínú ìpéjọpọ̀ ńlá,
2 “Yóò ti pẹ́ tó tí ìwọ yóò máa gbèjà àwọn aláìṣòdodo
3 Gbèjà àwọn aláìlágbára àti aláìní baba;
4 Gba àwọn aláìlágbára àti aláìní;
5 “Wọn kò mọ̀ ohun kankan,
6 “Mo wí pé, ‘Ẹyin ní “Ọlọ́run òrìṣà”;
7 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin ó kú bí ènìyàn lásán;
8 Dìde, Ọlọ́run, ṣe ìdájọ́ ayé,