Salmos 78

YOR

1 Ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ gbọ́ ẹ̀kọ́ mi;

2 Èmi ó la ẹnu mi ní òwe,

3 ohun tí a ti gbọ́ tí a sì ti mọ̀,

4 Àwa kì yóò pa wọ́n mọ́

5 Ó gbé ẹ̀rí kalẹ̀ ní Jakọbu

6 nítorí náà, àwọn ìran tí ń bọ̀ yóò mọ̀ wọ́n

7 Nígbà náà ni wọ́n ò fi ìgbẹ́kẹ̀lé wọn sínú Ọlọ́run

8 Kí wọn kí ó má ṣe dàbí àwọn baba ńlá wọn,

9 Àwọn ọkùnrin Efraimu, tí ó há mọ́ ọ tí wọ́n mú ọrun,

10 Wọn kò pa májẹ̀mú Ọlọ́run mọ́

11 Wọ́n gbàgbé ohun tí ó ti ṣe,

12 Ó ṣe ìyanu níwájú àwọn baba wọn ní ilẹ̀ Ejibiti, ní agbègbè Ṣoani.

13 Ó pín òkun ní yà, ó sì mú wọn kọjá

14 Ní ọ̀sán, ó fi ìkùùkuu àwọsánmọ̀ ṣe amọ̀nà wọn

15 Ó sán àpáta ní aginjù

16 Ó mú ìṣàn omi jáde láti inú àpáta

17 Wọ́n sì tún tẹ̀síwájú láti dẹ́ṣẹ̀ sí i

18 Wọ́n mọ̀ ọ́n mọ̀ dán Ọlọ́run wò

19 Wọ́n sọ̀rọ̀-òdì sí Ọlọ́run, wí pé

20 Nígbà tí ó lu àpáta, omi tú jáde,

21 Nígbà tí Olúwa gbọ́ wọn, ó bínú gidigidi;

22 nítorí wọn kò gba Ọlọ́run gbọ́,

23 Síbẹ̀ ó pàṣẹ fún ìràwọ̀ ojú ọ̀run,

24 Ó rọ manna fún àwọn ènìyàn láti jẹ,

25 Àwọn ènìyàn jẹ oúnjẹ àwọn angẹli;

26 Ó mú afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn láti ọ̀run wá

27 Ó rọ òjò ẹran sílẹ̀ sórí wọn bí erùpẹ̀ ilẹ̀,

28 Ó jẹ́ kí wọn jáde ní ibùdó wọn,

29 Wọ́n jẹ, wọ́n sì yó jọjọ

30 Ṣùgbọ́n wọn kò kúrò nínú oúnjẹ tí wọn fìtara bẹ̀bẹ̀ fún,

31 ìbínú Ọlọ́run dìde sí wọn

32 Nínú gbogbo ìwọ̀nyí, wọ́n ń dẹ́ṣẹ̀ síwájú;

33 O fi òpin sí ayé wọn nínú asán

34 Nígbàkígbà tí Ọlọ́run bá pa wọ́n,

35 Wọ́n rántí pé Ọlọ́run ní àpáta wọn;

36 Ṣùgbọ́n nígbà náà ni wọ́n yóò pọ́n ọn pẹ̀lú ẹnu wọ́n

37 ọkàn wọn kò sòtítọ́ sí i,

38 Síbẹ̀ ó ṣàánú;

39 Ó rántí pé ẹlẹ́ran ara ni wọ́n,

40 Nígbà gbogbo ní wọn ń ṣọ̀tẹ̀ sí i ní aginjù

41 Síwájú àti síwájú wọ́n dán Ọlọ́run wò;

42 Wọ́n kò rántí agbára rẹ̀:

43 ní ọjọ́ tí ó fi iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ hàn ní Ejibiti,

44 Ó sọ omi wọn di ẹ̀jẹ̀;

45 Ó rán ọ̀wọ́ eṣinṣin láti pa wọ́n run,

46 Ó fi ọkà wọn fún láńtata,

47 Ó fi yìnyín ba àjàrà wọn jẹ́

48 Ó fi ohun ọ̀sìn wọn fún yìnyín,

49 Ó mú kíkorò ìbínú rẹ̀ wá sí wọn lára,

50 Ó pèsè ipa fún ìbínú rẹ̀,

51 Ó kọlu àwọn àkọ́bí ọmọ ọkùnrin Ejibiti,

52 Ṣùgbọ́n ó mú àwọn ènìyàn rẹ̀ jáde bí ọ̀wọ́ ẹran;

53 Ó dáàbò bò wọ́n dáradára, nítorí náà ni ẹ̀rù kò ṣe bà wọ́n

54 Bákan náà ni ó mú wọn wá sí etí ilẹ̀ mímọ́ rẹ̀

55 Ó lé kèfèrí jáde níwájú wọn

56 Ṣùgbọ́n wọn dán Ọlọ́run wò

57 Ṣùgbọ́n wọ́n yípadà,

58 Wọ́n bí i nínú pẹ̀lú ibi gíga wọn;

59 Nígbà tí Ọlọ́run gbọ́ wọn,

60 Ó kọ àgọ́ Ṣilo sílẹ̀,

61 Ó rán àpótí ẹ̀rí, agbára rẹ̀ lọ sí ìgbèkùn,

62 Ó fi àwọn ènìyàn rẹ̀ lé idà lọ́wọ́,

63 Iná run àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin wọn,

64 àfi àlùfáà wọn fún idà,

65 Olúwa sì jí gẹ́gẹ́ bí ẹni ojú oorun,

66 Ó kọlu àwọn ọ̀tá rẹ̀ padà;

67 Nígbà náà ni ó kọ́ àgọ́ Josẹfu,

68 ṣùgbọ́n ó yan ẹ̀yà Juda,

69 Ó kọ́ ibi mímọ́ rẹ̀, ibi gíga,

70 Ó yan Dafidi ìránṣẹ́ rẹ̀

71 Ó mú un jáde nínú ìtọ́jú àgùntàn

72 Dafidi sì ṣọ́ wọn pẹ̀lú òtítọ́ inú ọkàn;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado