Salmos 77

YOR

1 Mó kígbe sí Ọlọ́run fún ìrànlọ́wọ́;

2 Nígbà tí mo wà nínú ìpọ́njú,

3 Èmi rántí rẹ, Ọlọ́run,

4 Ìwọ kò fẹ́ kí èmi fi ojú ba oorun,

5 Mo ronú nípa ọjọ́ ìgbàanì;

6 mo rántí orin mi ní òru.

7 “Olúwa yóò ha kọ̀ títí láé?

8 Ṣe ìfẹ́ rẹ̀ àti àánú rẹ̀ ti kú lọ láéláé?

9 Ọlọ́run ha gbàgbé láti máa ṣàánú?

10 Èmi wí pé, “Èyí ní ẹ̀dùn ọkàn mi,

11 Èmi ó rántí iṣẹ́ Olúwa:

12 Èmi ṣàṣàrò lórí iṣẹ́ rẹ gbogbo,

13 Ọlọ́run, ọ̀nà rẹ jẹ́ mímọ́.

14 Ìwọ ni Ọlọ́run tó ń ṣe ìyanu;

15 Pẹ̀lú ọwọ́ agbára rẹ ni ìwọ ra àwọn ènìyàn padà,

16 Nígbà tí àwọn omi rí Ọlọ́run,

17 Àwọn ojú ọ̀run tú omi sílẹ̀,

18 Àrá rẹ̀ ni a gbọ́ nínú ìjì,

19 Ipa rẹ̀ gba Òkun, ọ̀nà rẹ̀ ń bẹ nínú Òkun,

20 Ó tọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ ẹran

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado