1 A fi ìyìn fún ọ, Ọlọ́run,
2 Ìwọ wí pé, “Mo yan àkókò ìyàsọ́tọ̀;
3 Nígbà tí ayé àti àwọn ènìyàn ibẹ̀ wárìrì,
4 Èmí wí fún àwọn agbéraga pé,
5 Ẹ má ṣe gbe ìwo yín sókè sí ọ̀run;
6 Nítorí ìgbéga kò ti ìlà-oòrùn wá
7 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run ni olùdájọ́;
8 Ní ọwọ́ Olúwa ni ago kan wà,
9 Ṣùgbọ́n èmi, ó máa ròyìn rẹ títí láé;
10 Èmi ó gé ìwo gbogbo ènìyàn búburú,