Salmos 66

YOR

1 Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọ́run, ẹ̀yin ilẹ̀ gbogbo!

2 Ẹ kọrin ọlá orúkọ rẹ̀;

3 Ẹ wí fún Ọlọ́run pé, “Ìwọ ti ní ẹ̀rù tó nínú iṣẹ́ rẹ!

4 Gbogbo ayé ń wólẹ̀ fún ọ;

5 Ẹ wá wo ohun tí Ọlọ́run ṣe,

6 Ó yí òkun padà sí ilẹ̀ gbígbẹ,

7 Ó ń jẹ ọba títí láé nípa agbára rẹ̀,

8 Ẹ yin Ọlọ́run wa, ẹ̀yin ènìyàn,

9 Ó ti dá ààbò bo ẹ̀mí wa,

10 Nítorí ìwọ, Ọlọ́run, dán wa wò;

11 Ìwọ mú wa wá sínú ẹ̀wọ̀n

12 Ìwọ mú àwọn ènìyàn gún wá ní orí

13 Èmi ó wá sí tẹmpili rẹ pẹ̀lú ọrẹ ẹbọ sísun,

14 ẹ̀jẹ́ tí ètè mi jẹ́, tí ẹnu mi sì sọ

15 Èmi ó rú ẹbọ sísun ọlọ́ràá sí ọ,

16 Ẹ wá gbọ́ gbogbo ẹ̀yin tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run;

17 Mo fi ẹnu mi kígbe sókè sí i,

18 Bí èmi bá gba ẹ̀ṣẹ̀ ní àyà mi,

19 ṣùgbọ́n Ọlọ́run gbọ́ nítòótọ́

20 Ìyìn ni fún Ọlọ́run

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado