Salmos 65

YOR

1 Ìyìn ń dúró dè ọ́, Ọlọ́run, ní Sioni;

2 Ìwọ tí ó ń gbọ́ àdúrà,

3 Ọ̀ràn àìṣedéédéé borí mi bí ó ṣe ti ìrékọjá wa ni!

4 Ìbùkún ni fún àwọn tí o yàn

5 Ìwọ dá wa lóhùn pẹ̀lú ohun ìyanu ti òdodo,

6 ìwọ tí ó dá òkè nípa agbára rẹ,

7 ẹni tí ó mú rírú omi òkun dákẹ́,

8 Àwọn tí ó ń gbé òkèrè bẹ̀rù,

9 Ìwọ bẹ ayé wò, o sì bomirin;

10 Ìwọ fi bomirin sí aporo rẹ̀

11 Ìwọ fi oore rẹ dé ọdún ní adé,

12 Pápá tútù ní aginjù ń kan

13 Agbo ẹran ni a fi wọ pápá tútù náà ní aṣọ;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado