Salmos 62

YOR

1 Nínú Ọlọ́run nìkan ni ọkàn mi ti rí ìsinmi;

2 Òun nìkan ní àpáta mi àti ìgbàlà mi;

3 Ẹ̀yin ó ti máa kọ́lú ènìyàn kan pẹ́ tó?

4 Kìkì èrò wọn ni láti bì ṣubú

5 Nínú Ọlọ́run nìkan ni ìsinmi wà, ìwọ Ọlọ́run mi.

6 Òun nìkan ní àpáta àti ìgbàlà mi;

7 Ìgbàlà mi àti ògo mi dúró nínú Ọlọ́run;

8 Gbẹ́kẹ̀lé ní gbogbo ìgbà, ẹ̀yin ènìyàn;

9 Nítòótọ́, asán ni àwọn ọmọ ènìyàn,

10 Má ṣe gbẹ́kẹ̀lé ìnilára,

11 Ọlọ́run ti sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kejì,

12 pẹ̀lúpẹ̀lú, Olúwa, tìrẹ ni àánú;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado