Salmos 49

YOR

1 Ẹ gbọ́ èyí, gbogbo ènìyàn!

2 Àti ẹni tí ó ga àti ẹni tí ó kéré

3 Ẹnu mi yóò sọ̀rọ̀ ọgbọ́n,

4 èmi yóò dẹ etí mi sílẹ̀ sí òwe,

5 Èéṣe ti èmi yóò bẹ̀rù nígbà tí ọjọ́ ibi dé?

6 àwọn tí o gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ wọn,

7 Kò sí ọkùnrin tí ó lè ra ẹ̀mí ẹnìkejì rẹ̀

8 Nítorí ìràpadà fún ẹni jẹ́ iyebíye

9 ní ti kí ó máa wà títí ayé

10 Nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn rí ọkùnrin ọlọ́gbọ́n tí ó kú,

11 Ibojì wọn ni yóò jẹ́ ilé wọn láéláé,

12 Ṣùgbọ́n ọkùnrin tí o wà nínú ọlá kò dúró pẹ́

13 Èyí ni òtítọ́ àwọn ènìyàn tí ó

14 Gẹ́gẹ́ bí àgùntàn ni a tẹ́ wọn sínú isà òkú

15 Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò ra ọkàn mi padà

16 Má ṣe bẹ̀rù nígbà tí ẹnìkan bá di ọlọ́rọ̀.

17 Nítorí kì yóò mú ohun kan lọ nígbà tí ó bá kú,

18 Nígbà tí ó wà láyé, ó súre fún ọkàn ara rẹ̀.

19 Òun yóò lọ sí ọ̀dọ̀ ìran àwọn baba rẹ̀

20 Ọkùnrin tí ó ní ọlá tí kò ní òye dàbí ẹranko tí ó ṣègbé.

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado