1 Ẹni ńlá ní Olúwa, tí ó sì yẹ láti máa yìn
2 Ó dára nínú ipò ìtẹ́ rẹ̀,
3 Ọlọ́run wà nínú ààbò ààfin rẹ̀;
4 Nígbà tí àwọn ọba kógun jọ pọ̀,
5 Wọn rí i, bẹ́ẹ̀ ni ẹnu sì yà wọ́n,
6 Ẹ̀rù sì bà wọ́n níbẹ̀,
7 Ìwọ bà wọ́n jẹ́ gẹ́gẹ́ bí ọkọ̀ orí omi Tarṣiṣi,
8 Gẹ́gẹ́ bí a ṣe gbọ́,
9 Láàrín tẹmpili rẹ, Ọlọ́run,
10 Gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ Ọlọ́run,
11 Jẹ́ kí òkè Sioni kí ó yọ̀
12 Rìn Sioni kiri lọ yíká rẹ̀,
13 Kíyèsi odi rẹ̀,
14 Nítorí Ọlọ́run yìí Ọlọ́run wà ní títí ayé,