1 Ọkàn mi mọ ọ̀rọ̀ rere
2 Ìwọ yanjú ju àwọn ọmọ ènìyàn lọ:
3 Gba idà rẹ mọ́ ìhà rẹ, ìwọ alágbára jùlọ
4 Nínú ọláńlá rẹ, máa gẹṣin lọ ní àlàáfíà lórí òtítọ́,
5 Jẹ́ kí ọfà mímú rẹ̀ dá ọkàn àwọn ọ̀tá ọba lu
6 Ọlọ́run láé, àti láéláé ni ìtẹ́ rẹ,
7 Ìwọ fẹ́ olódodo, ìwọ sì kórìíra ìwà búburú
8 Gbogbo aṣọ rẹ̀ ni ó ń rùn pẹ̀lú òjìá àti aloe àti kasia;
9 Àwọn ọmọbìnrin àwọn ọba
10 Gbọ́ ìwọ ọmọbìnrin, ronú kí o sì dẹtí rẹ sí mi
11 Bẹ́ẹ̀ ni ọba yóò fẹ́ ẹwà rẹ gidigidi
12 Ọmọbìnrin ọba Tire yóò wá pẹ̀lú ẹ̀bùn
13 Gbogbo ògo ni ti ọmọbìnrin ọba ní àárín ilé rẹ̀,
14 Nínú aṣọ olówó iyebíye ni a mú un tọ́ ọba wá,
15 Wọ́n sì mú un wá pẹ̀lú ayọ̀ àti inú dídùn
16 Ọmọ rẹ̀ ni yóò gba ipò baba rẹ̀
17 Èmí yóò máa rántí orúkọ rẹ̀ ní ìran gbogbo,