1 Mo fi pẹ̀lẹ́pẹ̀lẹ́ dúró de Olúwa;
2 Ó fà mí yọ gòkè
3 Ó fi orin tuntun sí mi lẹ́nu,
4 Ayọ̀ ni fún àwọn wọ̀n-ọn-nì
5 Olúwa Ọlọ́run mi,
6 Ẹbọ àti ẹran ẹbọ ni ìwọ kò fẹ́,
7 Nígbà náà ni mo wí pé,
8 Mo ní inú dídùn
9 Èmi ti sọ ìròyìn ayọ̀ ti ìgbàlà
10 Èmi kò fi ìrànlọ́wọ́ ìgbàlà sin ní àyà mi;
11 Ìwọ má ṣe, fa àánú rẹ tí ó rọ́nú sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ mi Olúwa;
12 Nítorí pé àìníye ibi
13 Jẹ́ kí ó wù ọ́,
14 Gbogbo àwọn wọ̀n-ọn-nì ni kí ojú kí ó tì
15 Jẹ́ kí àwọn tí ó wí fún mi pé, “Háà! Háà!”
16 Jẹ́ kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ
17 Bí ó ṣe ti èmi ni,