Salmos 3

YOR

1 Olúwa, báwo ni àwọn ọ̀tá mi ṣe pọ̀ tó báyìí!

2 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó ń sọ ní ti tèmi, pé

3 Ṣùgbọ́n ìwọ ni asà yí mi ká, Olúwa;

4 Olúwa ni mo kígbe sókè sí,

5 Èmi dùbúlẹ̀, mo sì sùn;

6 Èmi kì yóò bẹ̀rù ẹgbẹẹgbẹ̀rún ènìyàn

7 Dìde, Olúwa!

8 Láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìgbàlà ti wá.

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado