Salmos 26

YOR

1 Ṣe ìdájọ́ mi, Olúwa,

2 Wádìí mi wò, Ìwọ Olúwa, kí o sì dán mi wò,

3 nítorí ìfẹ́ ẹ̀ rẹ tí ó dúró ṣinṣin ń bẹ níwájú mi,

4 Èmi kò jókòó pẹ̀lú aláìṣòótọ́,

5 Èmi ti kórìíra àwùjọ àwọn ènìyàn búburú

6 Èmí ó wẹ ọwọ́ mi ní àìlẹ́ṣẹ̀,

7 Èmi yóò kọrin sókè àní orin ọpẹ́,

8 Háà Olúwa, èmí ń fẹ́ ilé rẹ níbi tí ìwọ ń gbé,

9 Má ṣe gbá mi dànù pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,

10 àwọn tí ọwọ́ wọn kún fún ìwà ibi,

11 Ṣùgbọ́n èmi ó máa rìn nínú ìwà títọ́;

12 Ẹsẹ̀ mi dúró lórí ilẹ̀ tí ó tẹ́jú;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado