Salmos 20

YOR

1 Kí Olúwa kí ó gbóhùn rẹ ní ọjọ́ ìpọ́njú;

2 Kí ó rán ìrànlọ́wọ́ sí ọ, láti ibi mímọ́

3 Kí ó sì rántí gbogbo ẹbọ rẹ

4 Kí ó fi fún ọ gẹ́gẹ́ bi ti èrò ọkàn rẹ

5 Àwa yóò hó fún ayọ̀ nígbà tí o bá di aṣẹ́gun

6 Nísinsin yìí, èmi mọ̀ wí pé,

7 Àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé kẹ̀kẹ́, àwọn mìíràn gbẹ́kẹ̀ wọn lé ẹṣin,

8 Wọ́n wólẹ̀, ní eékún, wọ́n sì ṣubú,

9 Olúwa, fi ìṣẹ́gun fún ọba!

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado