Salmos 148

YOR

1 Ẹ fi ìyìn fún Olúwa.

2 Ẹ fi ìyìn fún un,

3 Ẹ fi ìyìn fún un,

4 Ẹ fi ìyìn fún un,

5 Ẹ jẹ́ kí wọn kí ó yin orúkọ Olúwa

6 Ó fi ìdí wọn múlẹ̀ láé àti láéláé

7 Ẹ yin Olúwa láti ilẹ̀ ayé wá

8 mọ̀nàmọ́ná àti òjò yìnyín

9 òkè ńlá àti gbogbo òkè kéékèèké,

10 àwọn ẹranko ńlá àti ẹran ọ̀sìn

11 àwọn ọba ayé àti ènìyàn ayé gbogbo

12 ọ̀dọ́mọkùnrin àti ọ̀dọ́mọbìnrin

13 Ẹ jẹ́ kí wọn kí ó yin orúkọ Olúwa

14 Ó sì gbé ìwo kan sókè fún àwọn ènìyàn rẹ̀,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado