1 Ọlọ́run, ọkàn mi dúró ṣinṣin
2 Jí ohun èlò orin àti haapu!
3 èmi ó yìn ọ́, Olúwa, nínú àwọn orílẹ̀-èdè,
4 Nítorí tí o tóbi ní àánú rẹ
5 Gbé ara rẹ ga, Ọlọ́run, lórí àwọn ọ̀run,
6 Kí a sì lè gba àwọn olùfẹ́ rẹ là;
7 Ọlọ́run ti sọ̀rọ̀ láti ibi mímọ́ rẹ̀ pé,
8 Gileadi ni tèmi, Manase ni tèmi,
9 Moabu sì ni ìkòkò ìwẹsẹ̀ mi,
10 Ta ni yóò mú mi wá sí ìlú olódi?
11 Ìwọ Ọlọ́run ha kọ́, ìwọ tí ó ti kọ̀ wá sílẹ̀.
12 Fún wa ní ìrànlọ́wọ́ nínú ìpọ́njú,
13 Nípasẹ̀ Ọlọ́run ni àwa ó ṣe akin