Salmos 109

YOR

1 Ọlọ́run, ti èmi ń fi ìyìn fún,

2 nítorí àwọn ènìyàn búburú àti ẹlẹ́tàn

3 Wọ́n fi ọ̀rọ̀ ìríra yí mi káàkiri;

4 Nípò ìfẹ́ mi, wọn ń ṣe ọ̀tá mi,

5 Wọ́n sì fi ibi san ìre fún mi

6 Yan àwọn ènìyàn búburú láti dojúkọ

7 Kí a dá a lẹ́bi nígbà tí a bá ṣe ìdájọ́

8 Kí ọjọ́ rẹ̀ kí ó kúrú;

9 Kí àwọn ọmọ rẹ̀ di aláìní baba

10 Jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ̀ máa ṣagbe kiri

11 Jẹ́ kí alọ́nilọ́wọ́gbà kí ó mú ohun gbogbo tí ó ní

12 Má ṣe jẹ́ kí ẹnìkan ṣe àánú fún un

13 Kí a gé àrọ́mọdọ́mọ rẹ̀ kúrò

14 Kí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn baba rẹ̀ kí

15 Jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ wọn kí ó wà ní ìrántí níwájú Olúwa

16 Nítorí kò rántí láti ṣàánú,

17 Ó fẹ́ràn láti máa mú ègún wá sí orí rẹ̀:

18 Bí ó ti fi ègún wọ ará rẹ̀ láṣọ bí ẹ̀wù

19 Jẹ́ kí ó rí fún un bí aṣọ tí a dà bò ó ní ara,

20 Èyí ni èrè àwọn ọ̀tá mi láti ọwọ́ Olúwa wá;

21 Ṣùgbọ́n ìwọ, ìwọ ṣe fún mi Olúwa Olódùmarè,

22 Nítorí pé tálákà àti aláìní ni mí,

23 Èmi ń kọjá lọ bí òjìji tí àṣálẹ́,

24 Eékún mi di aláìlera nítorí àwẹ̀ gbígbà

25 Mo dàbí ẹ̀gàn fún àwọn olùfisùn mi;

26 Ràn mí lọ́wọ́, Olúwa Ọlọ́run mi;

27 Jẹ́ kí wọn mọ̀ pé ọwọ́ rẹ ni èyí

28 Wọ́n ó máa gégùn ún, ṣùgbọ́n ìwọ máa súre,

29 Jẹ́ kí a wọ àwọn ọ̀tá mi ní aṣọ ìtìjú

30 Pẹ̀lú ẹnu mi èmi yóò máa yin Olúwa gidigidi

31 Nítorí ó dúró ní apá ọ̀tún aláìní

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado