1 Yin Olúwa! Ẹ fi ìyìn fún
2 Ta ni ó lè ròyìn iṣẹ́ agbára Olúwa,
3 Ìbùkún ni fún àwọn tí ń pa ìdájọ́ mọ́?
4 Rántí mi, Olúwa,
5 kí èmi kí ó lè jẹ ìgbádùn àlàáfíà àwọn tí ìwọ ti yàn,
6 Àwa ti dẹ́ṣẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn baba wa ti ṣe,
7 Nígbà tí àwọn baba wa wà ní Ejibiti,
8 Ṣùgbọ́n o gbà wọ́n là nítorí orúkọ rẹ
9 O bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;
10 O gbà wọ́n là kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn,
11 Omi ya lu àwọn ọ̀tá wọn;
12 Nígbà náà wọn gba ìpinnu rẹ gbọ́
13 Ṣùgbọ́n wọn kò pẹ́ gbàgbé ohun tí o ṣe
14 Nínú aginjù ni wọ́n tí ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́,
15 Nígbà náà, ó fún wọn ní ohun tí wọ́n béèrè fún
16 Nínú ibùdó ni wọ́n ṣe ìlara Mose
17 Ilẹ̀ la ẹnu ó sì gbé Datani mì
18 Ọwọ́ iná yọ ní ẹgbẹ́ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀;
19 Ní Horebu wọ́n ṣe ẹgbọrọ màlúù
20 Wọ́n pa ògo wọn dà
21 Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run, ẹni tí ó gbà wọ́n
22 iṣẹ́ ìyanu ní ilẹ̀ Hamu
23 Bẹ́ẹ̀ ni, ó sọ wí pé, òun yóò pa wọ́n run
24 Nígbà náà, wọ́n kẹ́gàn ilẹ̀ dídára náà
25 Wọ́n ń kùn nínú àgọ́ wọn
26 Bẹ́ẹ̀ ni ó búra fún wọn nípa gbígbé ọwọ́ rẹ̀ sókè
27 láti jẹ́ kí àwọn ọmọ rẹ̀ ṣubú lára orílẹ̀-èdè
28 Wọ́n da ara wọn pọ̀ mọ́ Baali-Peori,
29 wọ́n mú Ọlọ́run bínú pẹ̀lú ohun búburú tí wọn ń ṣe
30 Ṣùgbọ́n Finehasi dìde láti dá sí i,
31 A sì ka èyí sí òdodo fún un àti
32 Níbi omi Meriba, wọ́n bí Ọlọ́run nínú,
33 Nítorí tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí Ẹ̀mí Ọlọ́run.
34 Wọn kò pa àwọn ènìyàn run
35 Ṣùgbọ́n wọ́n dàpọ̀ mọ́ àwọn orílẹ̀-èdè,
36 Wọ́n sì sin àwọn òrìṣà wọn
37 Wọ́n fi àwọn ọmọkùnrin wọn rú ẹbọ
38 Wọ́n ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,
39 Wọ́n sì fi ìṣe wọn sọ ara wọn di aláìmọ́,
40 Nígbà náà ni Olúwa bínú sí àwọn ènìyàn rẹ̀
41 Ó sì fà wọ́n lé àwọn orílẹ̀-èdè lọ́wọ́,
42 Àwọn ọ̀tá wọn sì ń pọ́n wọn lójú
43 Ní ọ̀pọ̀ ìgbà òun gbà wọ́n,
44 Ṣùgbọ́n ó kíyèsi wọn nítorí ìṣòro
45 ó rántí májẹ̀mú rẹ̀ nítorí wọn
46 Lójú gbogbo àwọn tí ó kó wọn ní ìgbèkùn
47 Gbà wá, Olúwa Ọlọ́run wa,
48 Olùbùkún ni Olúwa,