1 Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Sefaniah ọmọ Kuṣi, ọmọ Gedaliah, ọmọ Amariah, ọmọ Hesekiah, ní ìgbà Josiah ọmọ Amoni ọba Juda.
2 “Èmi yóò mú gbogbo nǹkan kúrò
3 “Èmi yóò mú ènìyàn àti ẹranko kúrò;
4 “Èmi yóò na ọwọ́ mi sórí Juda
5 àti àwọn tí ń foríbalẹ̀ lórí òrùlé,
6 Àwọn tí ó yípadà kúrò lọ́dọ̀ Olúwa;
7 Ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú Olúwa Olódùmarè,
8 “Ní ọjọ́ ẹbọ Olúwa,
9 Ní ọjọ́ náà, èmi yóò fi ìyà jẹ
10 “Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí,
11 Ẹ hu, ẹ̀yin tí ń gbé ní agbègbè ọjà,
12 Ní àkókò wọ̀n-ọn-nì, èmi yóò wá Jerusalẹmu kiri pẹ̀lú fìtílà,
13 Nítorí náà, ọrọ̀ wọn yóò di ìkógun,
14 “Ọjọ́ ńlá Olúwa kù sí dẹ̀dẹ̀,
15 ọjọ́ náà yóò jẹ́ ọjọ́ ìbínú,
16 ọjọ́ ìpè àti ìpè ogun
17 “Èmi yóò sì mú ìpọ́njú wá sórí ènìyàn,
18 Bẹ́ẹ̀ ni fàdákà tàbí wúrà wọn