Provérbios 30

YOR

1 Àwọn ọ̀rọ̀ Aguri ọmọ Jake, ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ tí ọkùnrin yìí sọ fún Itieli.

2 “Èmi ni aláìmòye ju nínú àwọn ènìyàn;

3 Èmi kò tilẹ̀ kọ́ ọgbọ́n

4 Ta ni ó ti gòkè lọ sí ọ̀run tí ó sì padà sọ̀kalẹ̀?

5 “Gbogbo ọ̀rọ̀ Ọlọ́run jẹ́ aláìlábùkù;

6 Má ṣe fi kún ọ̀rọ̀ rẹ̀,

7 “Ohun méjì ni mo ń béèrè lọ́wọ́ rẹ, Olúwa;

8 Mú èké ṣíṣe àti irọ́ jìnnà sí mi;

9 Àìṣe bẹ́ẹ̀, mo lè ní àníjù kí n sì gbàgbé rẹ

10 “Má ṣe ba ìránṣẹ́ lórúkọ jẹ́ lọ́dọ̀ ọ̀gá rẹ̀,

11 “Àwọn kan wá ṣépè fún àwọn baba wọn

12 Àwọn tí ó mọ́ ní ojú ara wọn

13 àwọn ẹni tí ojú wọn gbéga nígbà gbogbo,

14 Àwọn ẹni tí eyín wọn jẹ́ idà

15 “Eṣúṣú ni ọmọbìnrin méjì.

16 Ibojì, inú tí ó yàgàn,

17 “Ojú tí ń fi baba ṣẹ̀fẹ̀,

18 “Àwọn nǹkan mẹ́ta wà tí ó jẹ́ ìyàlẹ́nu fún mi,

19 ipa ẹyẹ idì ní òfúrufú

20 “Èyí ni ọ̀nà alágbèrè obìnrin

21 “Lábẹ́ nǹkan mẹ́ta ni ilé ayé ti ń wárìrì

22 Ìránṣẹ́ tí ó di ọba

23 obìnrin tí gbogbo ènìyàn kórìíra tí ó sì wá lọ́kọ

24 “Àwọn ohun mẹ́rin ló kéré láyé

25 Àwọn èèrà jẹ́ aláìlágbára ẹ̀dá,

26 Ehoro jẹ́ aláìlágbára ẹ̀dá;

27 àwọn eṣú kò ní ọba,

28 Ọmọnílé fi ọwọ́ rẹ̀ dì mú,

29 “Àwọn ohun mẹ́ta ní ń bẹ tí ń rìn rere,

30 Kìnnìún, alágbára láàrín ẹranko tí kì í sá fún ohunkóhun

31 Ẹsin tí a dì lẹ́gbẹ̀ẹ́;

32 “Bí ìwọ bá ti hùwà aṣiwèrè nípa gbígbé ara rẹ ga,

33 Nítorí bí fífún omi ọmú tí í mú wàrà wá,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado