1 Ẹlẹ́yà ni ọtí wáìnì, aláriwo sì ní ọtí líle;
2 Ìbẹ̀rù ọba dàbí kíké e kìnnìún;
3 Iyì ni ó jẹ́ fún ènìyàn láti sá fún ìjà,
4 Ọ̀lẹ kì í ṣiṣẹ́ oko nígbà tí ó yẹ,
5 Ète ọkàn ènìyàn dàbí omi jíjìn;
6 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n máa ń sọ pe àwọn ní ìfẹ́ àìṣẹ̀tàn,
7 Olódodo ènìyàn a máa gbé ìgbé ayé àìlábùkù
8 Nígbà tí ọba bá jókòó sórí ìtẹ́ rẹ̀ láti ṣe ìdájọ́
9 Ta ni ó le è wí pé, “Mo ti ṣe ọkàn mi ní mímọ́,
10 Ìwọ̀n èké àti òsùwọ̀n ìrẹ́jẹ
11 Kódà a mọ ọmọdé nípa iṣẹ́ rẹ̀
12 Etí tí ó ń gbọ́ àti ojú tí ó ń ríran
13 Má ṣe fẹ́ràn oorun, àìṣe bẹ́ẹ̀ ìwọ yóò di tálákà.
14 “Kò dára, kò dára!” ní ẹni tó ra ọjà máa ń wí;
15 Wúrà wà, iyùn sì wà rẹpẹtẹ,
16 Gba abọ́ ẹni tí ó ṣe onídùúró fún àlejò;
17 Oúnjẹ tí a fi ọ̀nà èrú rí máa ń dùn lẹ́nu ènìyàn,
18 Pa ètè rẹ mọ́ nípa wíwá ìmọ̀ràn
19 Olófòófó a máa tú àṣírí
20 Bí ènìyàn kan bá ṣépè fún baba tàbí ìyá rẹ̀,
21 Ogún tí a kójọ kíákíá ní ìbẹ̀rẹ̀
22 Má ṣe wí pé, “N ó sẹ̀san àṣìṣe rẹ yìí fún ọ.”
23 Olúwa kórìíra òdínwọ̀n èké.
24 Olúwa ni ó ń ṣe olùdarí ìgbésẹ̀ ènìyàn.
25 Ìdẹ̀kùn ni fún ènìyàn láti ṣe ìlérí kíákíá
26 Ọlọ́gbọ́n ọba tú ènìyàn búburú ká;
27 Àtùpà Olúwa ń ṣe àwárí ẹ̀mí ènìyàn
28 Ìfẹ́ àti òdodo pa ọba mọ́,
29 Ògo àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin ni agbára wọn,
30 Ìgbájú ìgbámú àti ìfarapa máa ń mú ibi lọ,