Provérbios 19

YOR

1 Ó sàn kí ènìyàn jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ kò lábùkù

2 Kò dára láti ní ìtara láìní ìmọ̀,

3 Ìwà òmùgọ̀ ènìyàn fúnra rẹ̀ a pa ẹ̀mí rẹ̀ run;

4 Ọrọ̀ máa ń fa ọ̀rẹ́ púpọ̀;

5 Ajẹ́rìí èké kò ní lọ láìjìyà,

6 Ọ̀pọ̀ ń wá ojúrere olórí;

7 Gbogbo ará ilé e tálákà ni ó pa á tì,

8 Ẹni tí ó gba ọgbọ́n fẹ́ràn ọkàn ara rẹ̀;

9 Ajẹ́rìí èké kì yóò lọ láìjìyà

10 Kò yẹ aláìgbọ́n láti máa gbé nínú ọláńlá,

11 Ọgbọ́n ènìyàn a máa fún un ní sùúrù;

12 Ìbínú ọba dàbí kíké e kìnnìún,

13 Aṣiwèrè ọmọ jẹ́ ìparun baba rẹ̀,

14 A máa ń jogún ilé àti ọrọ̀ lọ́dọ̀ òbí,

15 Ọ̀lẹ ṣíṣe máa ń fa oorun sísùn fọnfọn,

16 Ẹnikẹ́ni tí ó gbọ́ ẹ̀kọ́ pa ẹnu rẹ̀ mọ́,

17 Ẹni tí ó ṣàánú tálákà, Olúwa ní ó yá,

18 Bá ọmọ rẹ wí nítorí nínú ìyẹn ni ìrètí wà;

19 Ènìyàn onínú-fùfù gbọdọ̀ gba èrè ìwà rẹ̀;

20 Fetí sí ìmọ̀ràn kí o sì gba ẹ̀kọ́,

21 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ète inú ọkàn ènìyàn,

22 Ohun tí ènìyàn ń fẹ́ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀;

23 Ìbẹ̀rù Olúwa ń mú ìyè wá;

24 Ọ̀lẹ ki ọwọ́ rẹ̀ bọ inú àwo oúnjẹ;

25 Na ẹlẹ́gàn, òpè yóò sì kọ́gbọ́n;

26 Ẹni tí ó ṣìkà sí baba rẹ̀, tí ó sì lé ìyá rẹ̀ jáde

27 Ọmọ mi, dẹ́kun láti tẹ́tí sí ẹ̀kọ́,

28 Ẹlẹ́rìí búburú fi ìdájọ́ ṣẹ̀sín,

29 A ti pèsè ìjìyà sílẹ̀ fún ẹlẹ́gàn;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado