Provérbios 13

YOR

1 Ọlọ́gbọ́n ọmọ gba ẹ̀kọ́ baba rẹ̀,

2 Láti inú èso ẹnu rẹ̀ ènìyàn ń gbádùn ohun rere,

3 Ẹnikẹ́ni tí ó ṣọ́ ẹnu rẹ̀ pa ẹnu ara rẹ̀ mọ́,

4 Ọkàn ọ̀lẹ ń fẹ́, ṣùgbọ́n kò rí nǹkan kan,

5 Olódodo kórìíra ohun tí í ṣe irọ́,

6 Òdodo ń ṣamọ̀nà ènìyàn olóòtítọ́ inú,

7 Ènìyàn kan díbọ́n bí ẹni tí ó ní ọrọ̀ síbẹ̀ kò ní nǹkan kan

8 Ọrọ̀ ènìyàn le è ra ẹ̀mí rẹ̀

9 Ìmọ́lẹ̀ olódodo tàn roro,

10 Ìgbéraga máa ń dá ìjà sílẹ̀ ni

11 Owó tí a fi ọ̀nà èrú kójọ yóò ṣí lọ,

12 Ìrètí tí ń falẹ̀ máa ń mú kí ọkàn ṣàárẹ̀

13 Ẹni tí ó kẹ́gàn ẹ̀kọ́ yóò jìyà rẹ̀

14 Ìkọ́ni ọlọ́gbọ́n jẹ́ orísun ìyè,

15 Òye pípé ń mú ni rí ojúrere,

16 Gbogbo olóye ènìyàn máa ń hùwà pẹ̀lú ìmọ̀,

17 Ìránṣẹ́ búburú bọ́ sínú ìdààmú

18 Ẹni tí ó kọ ìbáwí yóò di tálákà yóò sì rí ìtìjú,

19 Ìfẹ́ tí a mú ṣẹ dùn mọ́ ọkàn

20 Ẹni tí ó ń bá ọlọ́gbọ́n rìn yóò gbọ́n

21 Òsì a máa ta ẹlẹ́ṣẹ̀,

22 Ènìyàn rere a máa fi ogún sílẹ̀ fún àwọn ọmọ ọmọ rẹ̀,

23 Ilẹ̀ ẹ tálákà le è mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìre oko wá

24 Ẹni tí ó fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kórìíra ọmọ rẹ̀

25 Olódodo jẹ́wọ́ títí ó fi tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado