Oséias 13

YOR

1 Nígbà ti Efraimu bá ń sọ̀rọ̀, àwọn ènìyàn máa ń wárìrì,

2 Báyìí, wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀;

3 Nítorí náà wọn yóò dàbí ìkùùkuu òwúrọ̀,

4 “Ṣùgbọ́n Èmi ni Olúwa Ọlọ́run rẹ̀,

5 Mo ṣe ìtọ́jú rẹ ní aginjù,

6 Wọn ni ìtẹ́lọ́rùn nígbà tí mo fún wọn ní oúnjẹ,

7 Nítorí náà, Èmi yóò dìde sí wọn bí i kìnnìún,

8 Beari igbó tí a já ọmọ rẹ̀ gbà,

9 “A ti pa ọ́ run, ìwọ Israẹli,

10 Níbo ni ọba rẹ gbé wà nísinsin yìí kí ó bá à le gbà ọ là?

11 Nítorí èyí nínú ìbínú mi ni mo fún un yín ní ọba,

12 Ẹ̀bi Efraimu ni a tí ko jọ

13 Ìrora bí obìnrin tó fẹ́ bímọ ti dé bá a,

14 “Èmi yóò rà wọ́n padà kúrò lọ́wọ́ agbára isà òkú.

15 Bí ó tilẹ̀ gbilẹ̀ láàrín àwọn arákùnrin rẹ̀

16 Ará Samaria gbọdọ̀ ru ẹ̀bi wọn,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado