1 “Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọdé mo fẹ́ràn rẹ̀,
2 Bí a ti ń pe wọn,
3 Lóòtítọ́ mo kọ́ Efraimu pẹ̀lú ní ìrìn
4 Mo fi okùn ènìyàn fà wọ́n
5 “Ṣé wọn ò wá ní padà sí Ejibiti bí.
6 Idà yóò kọ mọ̀nà ní gbogbo ìlú wọn
7 Àwọn ènìyàn mi ti pinnu láti pẹ̀yìndà kúrò lọ́dọ̀ mi
8 “Báwo ni èmi ó ṣe fi ọ́ sílẹ̀, Efraimu?
9 Èmi kò ni mú ìbínú gbígbóná mi ṣẹ,
10 Wọn yóò máa tẹ̀lé Olúwa;
11 Wọn ó wá pẹ̀lú ẹ̀rù
12 Efraimu tí fi irọ́ yí mi ká