Oséias 10

YOR

1 Israẹli jẹ́ igi àjàrà tó gbilẹ̀

2 Ọkàn wọn kún fún ìtànjẹ

3 Nígbà náà ni wọn yóò wí pé, “A kò ní ọba

4 Wọ́n ṣe ìlérí púpọ̀,

5 Àwọn ènìyàn tí ń gbé Samaria bẹ̀rù

6 A ó gbé lọ sí Asiria

7 Bí igi tó léfòó lórí omi ni

8 Àwọn ibi gíga tí ẹ tí ń hùwà búburú ni a o parun,

9 “Láti ìgbà Gibeah, ni ó ti ṣẹ̀, ìwọ Israẹli,

10 Nígbà tó bá tẹ́ mi lọ́rùn, èmi yóò fi ìyà jẹ wọ́n;

11 Efraimu jẹ́ ọmọ abo màlúù tí a tí kọ́,

12 Ẹ gbin òdòdó fún ara yín,

13 Ṣùgbọ́n ẹ tí gbin búburú ẹ si ka ibi,

14 ariwo ogun yóò bo àwọn ènìyàn yín

15 Báyìí ni a o sì ṣe sí ọ, ìwọ Beteli,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado