Naum 1

YOR

1 Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ nípa Ninefe. Ìwé ìran Nahumu ará Elkoṣi.

2 Ọlọ́run ń jẹ owú, ó sì ń gbẹ̀san,

3 Olúwa lọ́ra láti bínú, ó sì tóbi ní agbára;

4 Ó bá òkun wí, ó sì mú kí ó gbẹ;

5 Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀,

6 Ta ni ó lé dúró níwájú ìbínú rẹ̀?

7 Rere ni Olúwa,

8 ṣùgbọ́n pẹ̀lú ìkún omi ńlá

9 Kí ni ẹ̀yìn ń gbìmọ̀ lòdì sí Olúwa?

10 Wọn yóò sì lọ́lù papọ̀ bí ẹ̀gún òṣùṣú

11 Láti ọ̀dọ̀ rẹ, ìwọ Ninefe, ni ẹnìkan ti jáde wá

12 Báyìí ni Olúwa wí:

13 Nísinsin yìí ni èmi yóò já àjàgà wọn kúrò ní ọrùn rẹ

14 Olúwa ti fi àṣẹ kan lélẹ̀ nítorí tìrẹ Ninefe:

15 Wò ó, lórí àwọn òkè,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado