1 Ègbé ni fún mi!
2 Àwọn olódodo sì ti kúrò ní ilẹ̀ náà,
3 Ọwọ́ wọn méjèèjì ti múra tán láti ṣe búburú;
4 Ẹni tí ó sàn jùlọ nínú wọn sì dàbí ẹ̀gún,
5 Ẹ má ṣe gba ọ̀rẹ́ kan gbọ́;
6 Nítorí tí ọmọkùnrin kò bọ̀wọ̀ fún baba rẹ̀,
7 Ṣùgbọ́n ní tèmi, èmi ní ìwòye ní ìrètí sí Olúwa,
8 Má ṣe yọ̀ mí, ìwọ ọ̀tá mi.
9 Nítorí èmi ti dẹ́ṣẹ̀ sí i,
10 Nígbà náà ni ọ̀tá mi yóò rí i
11 Ọjọ́ tí a ó mọ odi rẹ yóò dé,
12 Ní ọjọ́ náà àwọn ènìyàn yóò wá sọ́dọ̀ rẹ
13 Ilẹ̀ náà yóò di ahoro fún àwọn olùgbé inú rẹ̀,
14 Fi ọ̀pá rẹ bọ́ àwọn ènìyàn, agbo ẹran ìní rẹ,
15 “Bí i ọjọ́ tí ó jáde kúrò ní Ejibiti wá,
16 Orílẹ̀-èdè yóò rí i, ojú yóò sì tì wọ́n,
17 Wọn yóò lá erùpẹ̀ bí ejò,
18 Ta ni Ọlọ́run bí rẹ̀,
19 Òun yóò tún padà yọ́nú sí wa;
20 Ìwọ yóò fi òtítọ́ hàn sí Jakọbu