Miquéias 6

YOR

1 Ẹ fi etí sí ohun tí Olúwa wí:

2 “Gbọ́, ìwọ òkè ńlá, ẹ̀sùn Olúwa;

3 “Ẹ̀yin ènìyàn mi, kí ni mo ṣe fún yín?

4 Nítorí èmi mú un yín gòkè láti ilẹ̀ Ejibiti wá,

5 Ìwọ ènìyàn mi,

6 Kí ni èmi yóò ha mú wá síwájú Olúwa

7 Ǹjẹ́ Olúwa yóò ní inú dídùn sí ẹgbẹgbàarùn-ún àgbò,

8 Ó ti fihàn ọ́, ìwọ ènìyàn, ohun tí ó dára,

9 Gbọ́! Ohùn Olúwa kígbe sí ìlú ńlá náà,

10 Ǹjẹ́ ìṣúra ìwà búburú ha wà

11 Ǹjẹ́ èmi ha lè kà wọ́n sí mímọ́

12 Àwọn ọlọ́rọ̀ inú rẹ̀ kún fún ìwà ipá;

13 Nítorí náà ni èmi yóò ṣe mú ọ ṣàìsàn ní lílù ọ́,

14 Ìwọ yóò jẹun ṣùgbọ́n kì yóò yó;

15 Ìwọ yóò gbìn ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò kórè

16 Nítorí tí ìwọ ti pa òfin Omri mọ́,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado