Miquéias 2

YOR

1 Ègbé ni fún àwọn tí ń gbèrò àìṣedéédéé

2 Wọ́n sì ń ṣe ojúkòkòrò oko, wọ́n sì fi agbára wọn gbà wọ́n,

3 Nítorí náà, Olúwa wí pé:

4 Ní ọjọ́ náà ni ẹnìkan yóò pa òwe kan sí yín;

5 Nítorí náà, ìwọ kò ní ní ẹnìkankan tí yóò ta okùn nínú ìjọ Olúwa,

6 “Ẹ má ṣe sọtẹ́lẹ̀,” ni àwọn wòlíì wọn wí.

7 Ṣé kí á sọ ọ́, ìwọ ilé Jakọbu:

8 Láìpẹ́ àwọn ènìyàn mi dìde

9 Ẹ̀yin sì lé obìnrin àwọn ènìyàn mi

10 Ẹ dìde, kí ẹ sì máa lọ!

11 Tí òpùrọ́ àti ẹlẹ́tàn bá wà tí wọ́n sì wí pé,

12 “Èmi yóò kó gbogbo yín jọ, ìwọ Jakọbu;

13 Ẹni tí ó ń fọ ọ̀nà yóò lọ sókè níwájú wọn;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado