Jeremias 9

YOR

1 Háà! Orí ìbá jẹ́ orísun omi

2 Háà, èmi ìbá ní ni aginjù

3 Wọ́n ti pèsè ahọ́n wọn sílẹ̀

4 “Ṣọ́ra fún àwọn ọ̀rẹ́ rẹ;

5 Ọ̀rẹ́ ń dalẹ̀ ọ̀rẹ́. Kò sì ṣí ẹni

6 Ó ń gbé ní àárín ẹ̀tàn;

7 Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Àwọn ọmọ-ogun wí:

8 Ahọ́n wọn dàbí ọfà olóró;

9 Èmi kì yóò ha fi ìyà jẹ wọ́n nítorí èyí?”

10 Èmi yóò sì sọkún, pohùnréré ẹkún fún àwọn òkè

11 “Èmi yóò sì sọ Jerusalẹmu di òkìtì

12 Ta ni ẹni náà tí ó ní ọgbọ́n láti mòye nǹkan wọ̀nyí? Ta ni Olúwa ti sọ èyí fún, tí ó sì lè ṣàlàyé rẹ̀? Èéṣe tí ilẹ̀ náà fi ṣègbé bí aginjù, tí ẹnìkankan kò sì le là á kọjá?

13 Olúwa sì wí pé, nítorí pé wọ́n ti kọ òfin mi sílẹ̀, èyí tí mo gbé kalẹ̀ níwájú wọn, wọn ṣe àìgbọ́ràn sí wọn, wọn kò sì rìn nínú òfin mi.

14 Dípò èyí, wọ́n ti tẹ̀lé agídí ọkàn wọn, wọ́n ti tẹ̀lé Baali gẹ́gẹ́ bí àwọn baba wọn ṣe kọ́ wọn.

15 Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun, Ọlọ́run Israẹli wí, “Wò ó, Èmi yóò mú kí àwọn ènìyàn wọ̀nyí jẹ oúnjẹ kíkorò àti láti mu omi májèlé.

16 Èmi yóò sì tú wọn ká láàrín àwọn orílẹ̀-èdè, nínú èyí tí àwọn tàbí àwọn baba wọn kò mọ̀. Èmi yóò sì lépa wọn pẹ̀lú idà títí èmi yóò fi pa wọ́n run.”

17 Èyí sì ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun wí:

18 Jẹ́ kí wọn wá kíákíá,

19 A gbọ́ igbe ìpohùnréré

20 Nísinsin yìí, ẹ̀yin obìnrin ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa;

21 Ikú ti gba ojú fèrèsé wa wọlé

22 Sọ pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

23 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

24 Ẹ jẹ́ kí ẹni tí ń ṣògo nípa èyí nì wí pé:

25 “Ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa wí, “tí Èmi yóò fi ìyà jẹ gbogbo àwọn tí a kọ ilà fún nínú ara nìkan.

26 Ejibiti, Juda, Edomu, Ammoni, Moabu àti gbogbo àwọn tí ń gbé ní ọ̀nà jíjìn réré ní aginjù. Nítorí pé gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè wọ̀nyí jẹ́ aláìkọlà gbogbo àwọn ará ilé Israẹli sì jẹ́ aláìkọlà ọkàn.”

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado