1 “Lọ sókè àti sódò àwọn òpópó Jerusalẹmu,
2 Bí wọ́n tilẹ̀ wí pé, ‘Bí Olúwa ti ń bẹ,’
3 Olúwa, ojú rẹ kò ha wà lára òtítọ́?
4 Èmi sì rò pé, “Tálákà ni àwọn yìí;
5 Nítorí náà, èmi yóò tọ àwọn adarí lọ,
6 Nítorí náà, kìnnìún láti inú igbó yóò kọlù wọ́n,
7 “Kí ni ṣe tí èmi ó ṣe dáríjì ọ́?
8 Wọ́n jẹ́ akọ ẹṣin tí a bọ́ yó,
9 Èmi kì yóò ha ṣe ìbẹ̀wò nítorí nǹkan wọ̀nyí?”
10 “Lọ sí ọgbà àjàrà rẹ̀, kí ẹ sì pa wọ́n run,
11 Ilé Israẹli àti ilé Juda
12 Wọ́n ti pa irọ́ mọ́ Olúwa;
13 Àwọn wòlíì wá dàbí afẹ́fẹ́,
14 Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Alágbára wí:
15 Háà, ẹ̀yin ilé Israẹli,” ni Olúwa wí,
16 Apó-ọfà rẹ sì dàbí isà òkú tí a ṣí
17 Wọn yóò jẹ ìkórè rẹ àti oúnjẹ rẹ,
18 “Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì,” ni Olúwa wí, “Èmi kì yóò pa yín run pátápátá.
19 Àti pé, nígbà tí àwọn ènìyàn bá sì béèrè wí pé, ‘Kí ni ìdí rẹ̀ tí Olúwa Ọlọ́run wa fi ṣe gbogbo èyí sí wa?’ Ìwọ yóò sì sọ fún wọn wí pé, ‘Ẹ̀yin ti kọ̀ mí sílẹ̀, ẹ sì ń sin ọlọ́run àjèjì ní ilẹ̀ yín. Nísinsin yìí, ẹ̀yin yóò máa sin àjèjì ní ilẹ̀ tí kì í ṣe tiyín.’
20 “Kéde èyí fún ilé Jakọbu,
21 Gbọ́ èyí, ẹ̀yin aṣiwèrè àti aláìlọ́gbọ́n ènìyàn,
22 Kò ha yẹ kí ẹ bẹ̀rù mi?”
23 Ṣùgbọ́n, àwọn ènìyàn wọ̀nyí ní ọkàn líle àti ọkàn ọ̀tẹ̀,
24 Wọn kò sọ fún ara wọn pé,
25 Àìṣedéédéé yín mú gbogbo nǹkan wọ̀nyí kúrò,
26 “Láàrín ènìyàn mi ni ìkà ènìyàn wà
27 Bí àgò tí ó kún fún ẹyẹ,
28 wọ́n sanra wọ́n sì ń dán.
29 Èmi kì yóò ha fi ìyà jẹ wọ́n fún èyí bí?”
30 “Nǹkan ìbànújẹ́ àti ohun ìtara
31 Àwọn wòlíì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀ èké,