Jeremias 6

YOR

1 “Ẹ̀yin ènìyàn Benjamini, sá sí ibi ààbò!

2 Èmi yóò pa ọmọbìnrin Sioni run,

3 Olùṣọ́-àgùntàn pẹ̀lú agbo wọn yóò gbóguntì wọ́n.

4 “Ẹ ya ará yín sí mímọ́ láti bá a jagun!

5 Nítorí náà, ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí a kọlù ú ní àṣálẹ́

6 Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Àwọn ọmọ-ogun wí:

7 Gẹ́gẹ́ bí kànga ṣe ń da omi inú rẹ̀ sílẹ̀,

8 Ìwọ Jerusalẹmu, gba ìkìlọ̀,

9 Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí:

10 Ta ni ẹni tí mo lè bá sọ̀rọ̀ àti tí mo lè fún ní ìmọ̀ràn?

11 Èmi kún fún ìbínú Olúwa,

12 Ilé wọn o sì di ti ẹlòmíràn,

13 “Láti orí ẹni tí ó kéré sí orí ẹni tí ó tóbi ju,

14 Wọ́n sì ń wo ọgbẹ́ àwọn ènìyàn

15 Ojú ha a tì wọ́n nítorí ìwà ìríra wọn bí?

16 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:

17 Èmi yan olùṣọ́ fún un yín,

18 Nítorí náà, gbọ́ ẹ̀yin orílẹ̀-èdè;

19 Gbọ́, ìwọ ayé!

20 Èrè wo ni ó wà fún mi nínú tùràrí láti Ṣeba wá,

21 Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí:

22 Báyìí ni Olúwa wí:

23 Wọ́n sì dìmọ́ra pẹ̀lú ọrun àti ọ̀kọ̀,

24 Àwa ti gbọ́ ìròyìn nípa wọn,

25 Má ṣe jáde lọ sí orí pápá

26 Ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ gbé aṣọ ọ̀fọ̀ wọ̀,

27 “Èmi ti fi ẹ́ ṣe ẹni tí yóò máa yọ́

28 Ọlọ́tẹ̀ tí ọkàn rẹ̀ le ní gbogbo wọn.

29 Ewìrì a fẹ́ná kíkankíkan,

30 A pè wọ́n ní fàdákà tí a kọ̀sílẹ̀,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado