1 “Tí ìwọ yóò bá yí padà, ìwọ Israẹli, padà tọ̀ mí wá,”
2 Tí ó bá jẹ́ lóòtítọ́ àti òdodo ni ìwọ búra.
3 Èyí ni ohun tí Olúwa wí fún àwọn ènìyàn Juda àti Jerusalẹmu:
4 Kọ ara rẹ ní ilà sí Olúwa,
5 “Kéde ní Juda, kí o sì polongo ní Jerusalẹmu, kí o sì wí pé:
6 Fi àmì láti sálọ sí Sioni hàn,
7 Kìnnìún ti sá jáde láti inú ibùgbé rẹ̀,
8 Nítorí náà, gbé aṣọ ọ̀fọ̀ wọ̀
9 “Ní ọjọ́ náà,” ni Olúwa wí pé,
10 Nígbà náà ni mo sì wí pé, “Háà! Olúwa Olódùmarè, báwo ni ìwọ ti ṣe tan àwọn ènìyàn wọ̀nyí àti Jerusalẹmu jẹ nípa sísọ wí pé, ‘Ìwọ yóò wà ní àlàáfíà,’ nígbà tí o jẹ́ wí pé idà wà ní ọ̀fun wa.”
11 Nígbà náà ni a ó sọ fún Jerusalẹmu àti àwọn ènìyàn pé, “Ẹ̀fúùfù líle láti aṣálẹ̀ fẹ́ lu àwọn ènìyàn mi, kì í ṣe láti sọ di mímọ́.
12 Ẹ̀fúùfù líle tí ó wá láti ọ̀dọ̀ mi. Báyìí mo kéde ìdájọ́ mi lórí wọn.”
13 Wò ó! O ń bọ̀ bí ìkùùkuu
14 Ìwọ Jerusalẹmu, mú búburú kúrò lọ́kàn rẹ kí o sì yè.
15 Ohùn kan sì ń kéde ní Dani
16 “Sọ èyí fún àwọn orílẹ̀-èdè,
17 Wọ́n yí i ká bí ìgbà tí àwọn ọkùnrin bá ń ṣọ́ pápá,
18 “Ìwà rẹ àti ìṣe rẹ
19 Háà! Ìrora mi, ìrora mi!
20 Ìparun ń gorí ìparun;
21 Yóò ti pẹ́ tó, tí èmi yóò rí ogun
22 “Aṣiwèrè ni àwọn ènìyàn mi;
23 Mo bojú wo ayé,
24 Mo wo àwọn òkè ńlá,
25 Mo wò yíká n kò rí ẹnìkan;
26 Mo bojú wò, ilẹ̀ eléso, ó sì di aṣálẹ̀
27 Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
28 Nítorí náà, ayé yóò pohùnréré ẹkún
29 Nípa ariwo àwọn ẹlẹ́ṣin àti àwọn tafàtafà
30 Kí ni ò ń ṣe, ìwọ tí o ti di ìjẹ tán?
31 Mo gbọ́ ìró kan bí i igbe obìnrin tó ń rọbí,