Jeremias 48

YOR

1 Nípa Moabu.

2 Moabu kò ní ní ìyìn mọ́,

3 Gbọ́ igbe ní Horonaimu,

4 Moabu yóò di wíwó palẹ̀;

5 Wọ́n gòkè lọ sí Luhiti,

6 Sá! Àsálà fún ẹ̀mí yín;

7 Níwọ́n ìgbà tí o gbẹ́kẹ̀lé agbára àti ọrọ̀ rẹ,

8 Gbogbo ìlú rẹ ni apanirun yóò dojúkọ,

9 Fi iyọ̀ sí Moabu,

10 “Ìfibú ni fún ẹni tí ó fi ìmẹ́lẹ́ ṣe iṣẹ́ Olúwa,

11 “Moabu ti wà ní ìsinmi láti ìgbà èwe rẹ̀ wá

12 Ṣùgbọ́n ọjọ́ ń bọ̀,” ni Olúwa wí,

13 Nígbà náà Moabu yóò sì tú u nítorí Kemoṣi,

14 “Báwo ni o ṣe lè sọ pé, ‘Ajagun ni wá,

15 A ó pa Moabu run, a ó sì gba àwọn ìlú rẹ̀;

16 “Ìṣubú Moabu súnmọ́;

17 Ẹ dárò fún, gbogbo ẹ̀yin tí ó yí i ká

18 “Sọ̀kalẹ̀ níbi ògo rẹ,

19 Dúró lẹ́bàá ọ̀nà kí o sì wòran,

20 Ojú ti Moabu nítorí tí a wó o lulẹ̀.

21 Ìdájọ́ ti dé sí àwọn òkè pẹrẹsẹ,

22 sórí Diboni, Nebo àti Beti-Diblataimu,

23 sórí Kiriataimu, Beti-Gamu àti Beti-Meoni,

24 sórí Kerioti àti Bosra,

25 A gé ìwo Moabu kúrò,

26 “Ẹ jẹ́ kí a mú u mutí

27 Ǹjẹ́ Israẹli kò di ẹni ẹ̀gàn rẹ?

28 Kúrò ní àwọn ìlú rẹ, kí o sì máa gbé láàrín àwọn òkúta,

29 “A ti gbọ́ nípa ìgbéraga Moabu:

30 Mo mọ àfojúdi rẹ̀, ṣùgbọ́n òfo ni,” ni Olúwa wí,

31 Nítorí náà, mo pohùnréré ẹkún lórí Moabu

32 Mo sọkún fún ọ bí Jaseri ṣe sọkún

33 Ayọ̀ àti ìdùnnú ti kúrò

34 “Ohùn igbe wọn gòkè

35 Ní ti Moabu ni èmi yóò ti fi òpin sí

36 “Nítorí náà ọkàn mi ró fún Moabu bí fèrè,

37 Gbogbo orí ni yóò pá,

38 Ẹkún ńlá ní yóò wà lórí gbogbo òrùlé Moabu,

39 “Èéṣe tí ẹ fi fọ́ túútúú,

40 Báyìí ni Olúwa wí:

41 Kerioti ni a ó kó lẹ́rú àti ilé agbára ni ó gbà.

42 A ó pa Moabu run gẹ́gẹ́ bí

43 Ẹ̀rù àti ọ̀fìn àti okùn dídè

44 “Ẹnikẹ́ni tí ó bá sá fún

45 “Ní abẹ́ òjìji Heṣboni

46 Ègbé ní fún ọ Moabu!

47 “Síbẹ̀, èmi yóò dá ìkólọ

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado