Jeremias 49

YOR

1 Nípa Ammoni.

2 Ṣùgbọ́n ọjọ́ náà ń bọ̀,”

3 “Hu, ìwọ Heṣboni, nítorí Ai tí rún!

4 Èéṣe tí ìwọ fi ń ṣògo nínú àfonífojì rẹ,

5 Èmi yóò mu ẹ̀rù wá lórí rẹ

6 “Olúwa àwọn ọmọ-ogun.

7 Nípa Edomu.

8 Yípadà kí o sálọ, sá pamọ́ sínú ihò,

9 Tí àwọn tí ń ṣa èso bá tọ̀ ọ́ wá;

10 Ṣùgbọ́n èmi yóò tu Esau sí ìhòhò,

11 Fi àwọn ọmọ aláìní baba sílẹ̀

12 Èyí ni ohun tí Olúwa wí bí ẹnikẹ́ni tí kò bá yẹ kí ó mu ago náà bá mú un, kí ló dé tí ìwọ yóò fi lọ láìjìyà? Ìwọ kò ní lọ láìjìyà; ṣùgbọ́n ìwọ yóò mú un.

13 Èmi fi ara mi búra ni Olúwa wí, wí pé, “Bosra yóò ba ayé ara rẹ̀ jẹ́. Yóò di ẹni ẹ̀gàn, ẹni èpè àti ẹni ègún, àti gbogbo ìlú rẹ̀ yóò di ìbàjẹ́ títí láé.”

14 Ní gbígbọ́, èmi ti gbọ́ ìró kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa,

15 “Ní báyìí, èmi yóò sọ ọ́ di

16 Ìpayà tí ìwọ ti fà sínú

17 “Edomu yóò di ahoro

18 Gẹ́gẹ́ bí wọ́n ṣe gba Sodomu

19 “Bí i kìnnìún ni òun ó gòkè wá láti igbó Jordani sí orí ilẹ̀ ọlọ́ràá,

20 Nítorí náà, ẹ gbọ́ ohun tí

21 Ilẹ̀ yóò mì tìtì nípa ariwo ìṣubú wọn,

22 Wò ó! Ẹyẹ idì yóò gòkè fò wálẹ̀,

23 Nípa Damasku.

24 Damasku di aláìlera,

25 Kí ló dé tí ìlú olókìkí di ohun ìkọ̀sílẹ̀;

26 Lóòtítọ́, àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin rẹ yóò ṣubú lójú pópó,

27 “Èmi yóò fi iná sí odi Damasku,

28 Nípa ìlú Kedari àti ìjọba Hasori èyí ti Nebukadnessari ọba Babeli dojú ìjà kọ,

29 Àgọ́ wọn àti agbo àgùntàn wọn ni wọn ó kó lọ;

30 “Sálọ kíákíá!

31 “Dìde kí o sì dojú ìjà kọ orílẹ̀-èdè tí ó wà nínú ìrọ̀rùn,

32 Àwọn ìbákasẹ á di ẹrù

33 “Hasori yóò di ibi ìdọdẹ àwọn akátá,

34 Èyí ní ọ̀rọ̀ Olúwa èyí tí ó tọ Jeremiah wòlíì wá nípa Elamu ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Sedekiah ọba Juda.

35 Èyí ni ohun tí Olúwa àwọn ọmọ-ogun sọ:

36 Èmi yóò mú kí afẹ́fẹ́ orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin

37 Èmi yóò kẹ́gàn Elamu níwájú àwọn ọ̀tá wọn,

38 Èmi yóò sì gbé ìtẹ́ mi kalẹ̀ ní Elamu,

39 “Síbẹ̀, èmi yóò dá ìkólọ

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado