Jeremias 47

YOR

1 Èyí ni ọ̀rọ̀ Olúwa tó tọ wòlíì Jeremiah wá nípa àwọn Filistini, kí ó tó di pé Farao dojúkọ Gasa.

2 Báyìí ni Olúwa wí:

3 nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ìró títẹ̀lé pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin alágbára

4 Nítorí tí ọjọ́ náà ti pé

5 Gasa yóò fá irun orí rẹ̀ nínú ọ̀fọ̀.

6 “Ẹ̀yin kígbe, ‘Yé è, idà Olúwa,

7 Ṣùgbọ́n báwo ni yóò ṣe sinmi,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado