Jó 33

YOR

1 “Ǹjẹ́ nítorí náà, Jobu, èmí bẹ̀ ọ,

2 Kíyèsi i nísinsin yìí, èmí ya ẹnu mi,

3 Ọ̀rọ̀ mi yóò sì jásí ìdúró ṣinṣin ọkàn mi,

4 Ẹ̀mí Ọlọ́run ni ó tí dá mi,

5 Bí ìwọ bá le dá mi lóhùn,

6 kíyèsi i, bí ìwọ ṣe jẹ́ ti Ọlọ́run, bẹ́ẹ̀ ni èmi náà;

7 Kíyèsi i, ẹ̀rù ńlá mi kì yóò bà ọ;

8 “Nítòótọ́ ìwọ sọ ní etí mi,

9 ‘Èmi mọ́, láìní ìrékọjá, aláìṣẹ̀ ní èmi;

10 Kíyèsi i, Ọlọ́run ti rí àìṣedéédéé pẹ̀lú mi;

11 Ó kan ẹ̀ṣẹ̀ mi sínú àbà;

12 “Kíyèsi i, nínú èyí ìwọ ṣìnà!

13 Nítorí kí ni ìwọ ṣe ń bá a jà, wí pé,

14 Nítorí pe Ọlọ́run sọ̀rọ̀ lẹ́ẹ̀kan,

15 Nínú àlá, ní ojúran òru,

16 nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etí wọn,

17 kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínú ètè rẹ̀;

18 Ó sì fa ọkàn rẹ̀ padà kúrò nínú isà òkú,

19 “A sì nà án lórí ibùsùn ìrora rẹ̀;

20 bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mí rẹ kọ oúnjẹ,

21 Ẹran-ara rẹ̀ run, títí a kò sì fi lè rí i mọ́

22 Àní, ọkàn rẹ̀ sì súnmọ́ isà òkú,

23 Bí angẹli kan ba wà lọ́dọ̀ rẹ̀,

24 nígbà náà ni ó ṣe oore-ọ̀fẹ́ fún un ó sì wí pé,

25 Ara rẹ̀ yóò sì di ọ̀tun bí i ti ọmọ kékeré,

26 Ó gbàdúrà sọ́dọ̀ Ọlọ́run, òun sì ṣe ojúrere rẹ̀,

27 Ó wá sọ́dọ̀ ènìyàn ó sì wí pé,

28 Ọlọ́run ti gba ọkàn mi kúrò nínú lílọ sínú ihò,

29 “Wò ó! Nǹkan wọ̀nyí ni Ọlọ́run

30 láti mú ọkàn rẹ padà kúrò nínú isà òkú,

31 “Jobu, kíyèsi i gidigidi, kí o sì fetí sí mi;

32 Bí ìwọ bá sì ní ohun wí, dá mi lóhùn;

33 Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, gbọ́ tèmi;

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado