Jó 32

YOR

1 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí dákẹ́ láti dá Jobu lóhùn, nítorí ó ṣe olódodo lójú ara rẹ̀.

2 Nígbà náà ni inú bí Elihu ọmọ Barakeli ará Busi, láti ìbátan ìdílé Ramu; ó bínú si Jobu nítorí ti ó dá ara rẹ̀ láre kàkà ki ó dá Ọlọ́run láre.

3 Inú sì bí i sí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, nítorí tí wọn kò rí ọ̀nà láti dá Jobu lóhùn bẹ́ẹ̀ ni wọ́n dá Jobu lẹ́bi.

4 Ǹjẹ́ Elihu ti dúró títí tí Jobu fi sọ̀rọ̀ tán nítorí tí àwọn wọ̀nyí dàgbà ju òun lọ ní ọjọ́ orí.

5 Nígbà tí Elihu rí i pé ìdáhùn ọ̀rọ̀ kò sí ní ẹnu àwọn ọkùnrin mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí nígbà náà ni ó bínú.

6 Elihu, ọmọ Barakeli, ará Busi, dáhùn ó sì wí pé,

7 Èmi wí pé ọjọ́ orí ni ìbá sọ̀rọ̀,

8 Ṣùgbọ́n ẹ̀mí kan ní ó wà nínú ènìyàn

9 Ènìyàn ńlá ńlá kì í ṣe ọlọ́gbọ́n,

10 “Nítorí náà ní èmí ṣe wí pé, ẹ dẹtí sílẹ̀ sí mi;

11 Kíyèsi i, èmí ti dúró de ọ̀rọ̀ yín;

12 àní, mo fiyèsí yín tinútinú.

13 Kí ẹ̀yin kí ó má ṣe wí pé, ‘Àwa wá ọgbọ́n ní àwárí;

14 Bí òun kò ti sọ̀rọ̀ sí mi,

15 “Ẹnu sì yà wọ́n, wọn kò sì dáhùn mọ́,

16 Mo sì retí, nítorí wọn kò sì fọhùn, wọ́n dákẹ́ jẹ́ẹ́;

17 Bẹ́ẹ̀ ni èmí ó sì dáhùn nípa ti èmi,

18 Nítorí pé èmi kún fún ọ̀rọ̀ sísọ,

19 Kíyèsi i, ikùn mi dàbí ọtí wáìnì, tí kò ní ojú-ìhò;

20 Èmí ó sọ, kí ara kí ó le rọ̀ mí,

21 Lóòtítọ́ èmi kì yóò ṣe ojúsàájú sí ẹnìkankan,

22 Nítorí pé èmí kò mọ̀ ọ̀rọ̀ ìpọ́nni í sọ ní ṣíṣe bẹ́ẹ̀,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado