Jó 31

YOR

1 “Mo ti bá ojú mi dá májẹ̀mú,

2 Nítorí pé kí ni ìpín Ọlọ́run láti ọ̀run wá?

3 Kò ṣe pé àwọn ènìyàn búburú ni ìparun wà fún,

4 Òun kò ha ri ipa ọ̀nà mi,

5 “Bí ó bá ṣe pé èmi bá fi àìṣòótọ́ rìn,

6 (jẹ́ kí Ọlọ́run wọ́n mí nínú ìwọ̀n òdodo,

7 Bí ẹsẹ̀ mí bá yà kúrò lójú ọ̀nà,

8 ǹjẹ́ kí èmi kí ó gbìn kí ẹlòmíràn kí ó sì mújẹ,

9 “Bí àyà mi bá di fífà sí ipasẹ̀ obìnrin kan,

10 kí àyà mi kí ó lọ ọlọ fún ẹlòmíràn,

11 Nítorí pé yóò jẹ́ ohun ìtìjú àní,

12 Nítorí pé iná ní èyí tí ó jó dé ibi ìparun,

13 “Tí mo bá sì ṣe àìka ọ̀ràn ìránṣẹ́kùnrin mi

14 kí ni èmi ó ha ṣe nígbà tí Ọlọ́run bá dìde?

15 Ẹni tí ó dá mi ní inú kọ́ ni ó dá a?

16 “Bí mo bá fa ọwọ́ sẹ́yìn fún ìfẹ́ inú tálákà,

17 tàbí tí mo bá nìkan bu òkèlè mi jẹ,

18 nítorí pé láti ìgbà èwe mi wá ni a ti tọ́ ọ dàgbà pẹ̀lú mi bí ẹni pé baba,

19 bí èmi bá rí olùpọ́njú láìní aṣọ,

20 bí ọkàn rẹ̀ kò bá súre fún mi,

21 bí mo bá sì gbé ọwọ́ mi sókè sí aláìní baba,

22 ǹjẹ́, ní apá mi kí o wọ́n kúrò ní ihò èjìká rẹ̀,

23 Nítorí pé ìparun láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wá ni ẹ̀rù ńlá fún mi,

24 “Bí ó bá ṣe pé mo fi wúrà ṣe ìgbẹ́kẹ̀lé mi,

25 bí mo bá yọ̀ nítorí ọrọ̀ mí pọ̀,

26 bí mo bá bojú wo oòrùn nígbà tí ń ràn,

27 bí a bá tàn ọkàn mi jẹ

28 èyí pẹ̀lú ni ẹ̀ṣẹ̀ ti àwọn onídàájọ́ ní láti bẹ̀wò,

29 “Bí ó bá ṣe pé mo yọ̀ sì ìparun ẹni tí ó kórìíra mi.

30 Bẹ́ẹ̀ èmi kò sì jẹ ki ẹnu mi ki ó ṣẹ̀

31 Bí àwọn ènìyàn inú àgọ́ mi kò bá lè wí pé,

32 Àlejò kò wọ̀ ni ìgboro rí;

33 Bí mo bá bò ẹ̀ṣẹ̀ mi mọ́lẹ̀ bí Adamu ni pápá,

34 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni mo ha bẹ̀rù bí?

35 (“Ìbá ṣe pé ẹnìkan le gbọ́ ti èmí!

36 Nítòótọ́ èmí ìbá gbé le èjìká mi,

37 Èmi ìbá sì sọ iye ìṣísẹ̀ mi fún un,

38 “Bí ilẹ̀ mi bá sì ké rara lòdì sí mi

39 Bí mo bá jẹ èso oko mi láìsan owó

40 kí ẹ̀gún òṣùṣú kí ó hù dípò alikama,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado