Jó 21

YOR

1 Jobu wá dáhùn, ó sì wí pé,

2 “Ẹ tẹ́tí sílẹ̀ dáradára sì àwọn ọ̀rọ̀ mi,

3 Ẹ jọ̀wọ́ mi ki èmi sọ̀rọ̀;

4 “Àròyé mi ha ṣe sí ènìyàn bí?

5 Ẹ wò mí fín, kí ẹnu kí ó sì yà yín,

6 Àní nígbà tí mo rántí, ẹ̀rù bà mí,

7 Nítorí kí ní ènìyàn búburú fi wà ní ayé,

8 Irú-ọmọ wọn fi ìdí kalẹ̀ ní ojú

9 Ilé wọn wà láìní ewu àti ẹ̀rù,

10 Akọ màlúù wọn a máa gùn, kì í sì tàsé;

11 Wọn a máa rán àwọn ọmọ wọn

12 Wọ́n mú ohun ọ̀nà orin, ìlù àti haapu;

13 Wọ́n n lo ọjọ́ wọn nínú ọrọ̀;

14 Nítorí náà ni wọ́n ṣe wí fún Ọlọ́run pé, ‘Lọ kúrò lọ́dọ̀ wa!’

15 Kí ni Olódùmarè tí àwa ó fi máa sìn in?

16 Kíyèsi i, àlàáfíà wọn kò sí nípa ọwọ́ wọn;

17 “Ìgbà mélòó mélòó ní a ń pa fìtílà ènìyàn búburú kú?

18 Wọ́n dàbí àgékù koríko níwájú afẹ́fẹ́,

19 Ẹ̀yin wí pé, ‘Ọlọ́run to ìyà ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ jọ fún àwọn ọmọ rẹ̀.’

20 Ojú rẹ̀ yóò rí ìparun ara rẹ̀,

21 Nítorí pé àlàáfíà kí ni ó ní nínú ilé rẹ̀ lẹ́yìn rẹ̀,

22 “Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni le kọ Ọlọ́run ní ìmọ̀?

23 Ẹnìkan a kú nínú pípé agbára rẹ̀,

24 Ọpọ́n rẹ̀ kún fún omi ọmú,

25 Ẹlòmíràn a sì kú nínú kíkorò ọkàn rẹ̀,

26 Wọ́n o dùbúlẹ̀ bákan náà nínú erùpẹ̀,

27 “Kíyèsi i, èmi mọ̀ èrò inú yín àti

28 Nítorí tí ẹ̀yin wí pé, ‘Níbo ní ilé ọmọ-aládé,

29 Ẹ̀yin kò béèrè lọ́wọ́ àwọn tí ń kọjá lọ ní ọ̀nà?

30 pé ènìyàn búburú ní a fi pamọ́ fún ọjọ́ ìparun.

31 Ta ni yóò tako ipa ọ̀nà rẹ̀ lójúkojú,

32 Síbẹ̀ a ó sì sin ín ní ọ̀nà ipò òkú,

33 Ògúlùtu àfonífojì yóò dùn mọ́ ọn.

34 “Èéha ti ṣe tí ẹ̀yin fi ń tù mí nínú lásán,

Ler em outra tradução

Comparar lado a lado