1 Ìgbà náà ni Jobu dáhùn, ó sì wí pé:
2 “Yóò ti pẹ́ tó tí ẹ̀yin ó fi máa fi ìyà jẹ mí,
3 Ìgbà mẹ́wàá ní yin yọ mi lénu ẹ̀yin ti ń gàn mí;
4 Kí a sì wí bẹ́ẹ̀ pé, mo ṣìnà nítòótọ́,
5 Bí ó tilẹ̀ ṣe pé ẹ̀yin ó ṣògo si mi lórí nítòótọ́,
6 kí ẹ mọ̀ nísinsin yìí pé, Ọlọ́run ni ó bì mí ṣubú,
7 “Kíyèsi, èmi ń kígbe pe, ‘Ọwọ́ alágbára!’ Ṣùgbọ́n a kò gbọ́ ti èmi;
8 Ó ṣọgbà dí ọ̀nà mi tí èmi kò le è kọjá,
9 Ó ti bọ́ ògo mi,
10 Ó ti bà mí jẹ́ ní ìhà gbogbo,
11 Ó sì tiná bọ ìbínú rẹ̀ sí mi,
12 Ẹgbẹ́ ogun rẹ̀ sì dàpọ̀ sí mi,
13 “Ó mú àwọn arákùnrin mi jìnà sí mi réré,
14 Àwọn alájọbí mi fàsẹ́yìn,
15 Àwọn ará inú ilé mi àti àwọn ìránṣẹ́bìnrin mi kà mí sí àjèjì;
16 Mo pe ìránṣẹ́ mi, òun kò sì dá mi lóhùn;
17 Ẹ̀mí mi ṣú àyà mi, àti òórùn mi
18 Àní àwọn ọmọdékùnrin fi mí ṣẹ̀sín,
19 Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ kòríkòsùn mi kórìíra mi,
20 Egungun mi lẹ̀ mọ́ ara mi àti mọ́ ẹran-ara mi,
21 “Ẹ ṣàánú fún mi, ẹ ṣàánú fún mi,
22 Nítorí kí ni ẹ̀yin ṣe lépa mi bí
23 “Háà! Ìbá ṣe pé a le kọ̀wé ọ̀rọ̀ mi nísinsin yìí,
24 Kí a fi kálámù irin àti ti òjé kọ
25 Nítorí èmi mọ̀ pé olùdáǹdè mi ń bẹ láààyè
26 àti lẹ́yìn ìgbà tí a pa àwọ̀ ara mi run,
27 ẹni tí èmi ó rí fún ara mi,
28 “Bí ẹ̀yin bá wí pé, ‘Àwa ó ti lépa rẹ̀ tó!
29 kí ẹ̀yin kí ó bẹ̀rù,