1 Ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó tọ Joẹli ọmọ Petueli wá.
2 Ẹ gbọ́ èyí ẹ̀yin àgbàgbà;
3 Ẹ sọ ọ́ fún àwọn ọmọ yín,
4 Èyí tí eṣú tí agénijẹ jẹ kù
5 Ẹ jí gbogbo ẹ̀yin ọ̀mùtí kí ẹ sì sọkún
6 Nítorí orílẹ̀-èdè kan ti ṣígun sí ilẹ̀ mìíràn
7 Ó ti pa àjàrà mi run,
8 Ẹ pohùnréré ẹkún bí wúńdíá
9 A ké ọrẹ jíjẹ́ àti ọrẹ mímu
10 Oko di ìgboro, ilẹ̀ ń ṣọ̀fọ̀,
11 Kí ojú kí ó tì yín, ẹ̀yin àgbẹ̀;
12 Àjàrà gbẹ, igi ọ̀pọ̀tọ́ sì rọ̀ dànù;
13 Ẹ di ara yín ni àmùrè,
14 Ẹ yà àwẹ̀ kan sí mímọ́,
15 A! Fún ọjọ́ náà,
16 A kò ha ké oúnjẹ kúrò níwájú
17 Irúgbìn bàjẹ́ nínú ebè wọn,
18 Àwọn ẹranko tí ń kérora tó!
19 Olúwa, sí ọ ni èmi o ké pè,
20 Àwọn ẹranko igbó gbé ojú sókè sí ọ pẹ̀lú,