1 “Èmi fi ara mi hàn fún àwọn tí kò béèrè fún mi;
2 Gbogbo ọjọ́ ni mo ti nawọ́ mi síta
3 àwọn ènìyàn tí wọ́n bí mi nínú nígbà gbogbo
4 wọ́n ń jókòó láàrín ibojì
5 tí ó wí pé, ‘Ẹ sún mẹ́yìn; ẹ má wá sọ́dọ̀ mi,
6 “Kíyèsi i, a ti kọ ọ́ síwájú mi,
7 àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín àti tàwọn baba yín,”
8 Báyìí ni Olúwa wí:
9 Èmi yóò mú ìrandíran wá láti ìdílé Jakọbu,
10 Ṣaroni yóò di pápá oko fún ọ̀wọ́ ẹran,
11 “Ṣùgbọ́n fún ẹ̀yin tí ó kọ Olúwa sílẹ̀
12 Èmi yóò yà ọ́ sọ́tọ̀ fún idà,
13 Nítorí náà, báyìí ni Olúwa Olódùmarè wí:
14 Àwọn ìránṣẹ́ mi yóò kọrin
15 Ẹ̀yin yóò fi orúkọ yín sílẹ̀
16 Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbàdúrà ìbùkún ní ilẹ̀ náà
17 “Kíyèsi i, Èmi yóò dá
18 Ṣùgbọ́n ẹ yọ̀ kí inú yín dùn títí láé
19 Èmi yóò ṣe àjọyọ̀ lórí Jerusalẹmu
20 “Títí láé a kì yóò gbọ́ nínú rẹ̀
21 Wọn yó ò kọ́ ilé, wọn yóò sì gbé nínú wọn
22 Wọn kì yóò kọ́ ilé fún ẹlòmíràn láti gbé,
23 Wọn kì yóò ṣe iṣẹ́ lásán,
24 Kí wọn tó pè, èmi yóò dáhùn;
25 Ìkookò àti ọ̀dọ́-àgùntàn yóò jẹun pọ̀,