1 “Kígbe rẹ̀ sókè, má ṣe fàsẹ́yìn.
2 Nítorí ọjọ́ dé ọjọ́ ni wọ́n ń wá mi kiri;
3 Wọ́n wí pé, ‘Èéṣe tí àwa fi ń gbààwẹ̀,
4 Àwẹ̀ yín sì parí nínú ìjà àti asọ̀,
5 Ǹjẹ́ èyí ha ni irú àwẹ̀ tí mo yàn bí,
6 “Ǹjẹ́ irú àwẹ̀ tí mo ti yàn kọ́ ni èyí:
7 Kì í ha á ṣe láti pín oúnjẹ yín fún àwọn tí ebi ń pa
8 Nígbà náà ni ìmọ́lẹ̀ rẹ yóò tàn jáde bí òwúrọ̀
9 Nígbà yìí ni ẹ̀yin yóò pè, tí Olúwa yóò sì dáhùn;
10 àti bí ẹ̀yin bá ná ara yín bí owó nítorí àwọn tí ebi ń pa
11 Olúwa yóò máa tọ́ ọ yín nígbà gbogbo;
12 Àwọn ènìyàn rẹ yóò tún ahoro àtijọ́ kọ́
13 “Bí ìwọ bá pa ẹsẹ̀ rẹ mọ́ kúrò nínú bíba ọjọ́ ìsinmi jẹ́,
14 nígbà náà ni ìwọ yóò ní ayọ̀ nínú Olúwa rẹ,