1 Lódodo ọwọ́ Olúwa kò kúrú láti gbàlà,
2 Ṣùgbọ́n ẹ̀ṣẹ̀ yín ló ti yà yín kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run yín;
3 Nítorí ọwọ́ yín di aláìmọ́ fún ẹ̀jẹ̀,
4 Kò sí ẹni tí ó béèrè fún ìdájọ́ òdodo;
5 Wọn ń pa ẹ̀yin paramọ́lẹ̀
6 Òwú wọn kò wúlò fún aṣọ rírán;
7 Ẹsẹ̀ wọn yára bọ́ sínú ẹ̀ṣẹ̀;
8 Ọ̀nà àlàáfíà èyí ni wọn kò mọ̀;
9 Nítorí èyí ni ẹ̀tọ́ fi jìnnà sí wa,
10 Gẹ́gẹ́ bí afọ́jú à ń táràrà lọ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ògiri
11 Gbogbo wa là ń ké bí i beari;
12 Nítorí àwọn àṣìṣe wa pọ̀ níwájú rẹ,
13 ọ̀tẹ̀ àti àrékérekè wa sí Olúwa,
14 Nítorí èyí ni a ṣe lé ìdájọ́ òdodo sẹ́yìn,
15 A kò rí òtítọ́ mọ́,
16 Òun rí i pé kò sí ẹnìkan,
17 Ó gbé òdodo wọ̀ gẹ́gẹ́ bí ìgbàyà rẹ̀,
18 Gẹ́gẹ́ bí ohun tí wọ́n ti ṣe,
19 Láti ìwọ̀-oòrùn, àwọn ènìyàn yóò bẹ̀rù orúkọ Olúwa,
20 “Olùdáǹdè yóò wá sí Sioni,
21 “Àti fún èmi, májẹ̀mú mi pẹ̀lú wọn nìyìí,” ni Olúwa wí, “Ẹ̀mí mi, tí ó wà nínú yín, àti ọ̀rọ̀ mi tí mo ti fi sí ẹnu yín, kì yóò kúrò lẹ́nu yín, tàbí lẹ́nu àwọn ọmọ yín, tàbí láti ẹnu àwọn ìrandíran wọn láti àkókò yìí lọ àti títí láéláé,” ni Olúwa wí.